YOR Job Chương 34

Job 34

YOR · So sánh · Âm thanh

1Nígbà náà ni Elihu dáhùn, ó sì wí pé, 2“Ẹ̀yin ọlọ́gbọ́n ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, 3Nítorí pé etí a máa dán ọ̀rọ̀ wò, 4Ẹ jẹ́ kí a mọ òye ohun tí o tọ́ fún ara wa; 5“Nítorí pé Jobu wí pé, ‘Aláìlẹ́ṣẹ̀ ni èmi; 6Èmi ha purọ́ sí ẹ̀tọ́ mi bí, 7Ọkùnrin wo ni ó dàbí Jobu, 8Tí ń bá àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kẹ́gbẹ́ tí ó 9Nítorí ó sá ti wí pé, ‘Èrè kan kò sí fún ènìyàn, 10“Ǹjẹ́ nítorí náà, ẹ fetísílẹ̀ sí mi, 11Nítorí pé ó ń sán fún ènìyàn fún gẹ́gẹ́ bi ohun tí a bá ṣe, 12Nítòótọ́ Ọlọ́run kì yóò hùwàkiwà; 13Ta ni ó fi ìtọ́jú ayé lé e lọ́wọ́, 14Bí ó bá gbé ayé rẹ̀ lé kìkì ara rẹ̀ 15gbogbo ènìyàn ni yóò parun pọ̀, 16“Ǹjẹ́ nísinsin yìí, bí ìwọ bá ní òye, 17Ẹni tí ó kórìíra òtítọ́ ha le ṣe olórí bí? 18O ha tọ́ láti wí fún ọba pé, ‘Ènìyàn búburú ní ìwọ,’ 19mélòó mélòó fún ẹni tí kì í ṣe ojúsàájú àwọn ọmọ-aládé 20Ní ìṣẹ́jú kan ni wọn ó kú, 21“Nítorí pé ojú rẹ̀ ń bẹ ní ipa ọ̀nà ènìyàn, 22Kò sí ibi òkùnkùn, tàbí òjìji ikú, 23Nítorí pé òun kò pẹ́ àti kíyèsi ẹnìkan, 24Òun ó sì fọ́ àwọn alágbára túútúú láìní ìwádìí, 25nítorí pé ó mọ iṣẹ́ wọn, 26Ó kọlù wọ́n nítorí ìwà búburú wọn 27nítorí pé wọ́n padà pẹ̀yìndà sí i, 28kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkún àwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, 29Ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi? 30kí aláìwà bi Ọlọ́run kí ó má bá à jẹ ọba 31“Nítorí pé ẹnìkan ha lè wí fún Ọlọ́run pé, 32Èyí tí èmi kò rí ìwọ fi kọ́ mi 33Ǹjẹ́ bí ti inú rẹ̀ ni ki òun ó san ẹ̀ṣẹ̀ padà? 34“Àwọn ènìyàn amòye yóò wí fún mi, 35‘Jobu ti fi àìmọ̀ sọ̀rọ̀, 36Ìfẹ́ mi ni kí a dán Jobu wò dé òpin, 37Nítorí pe ó fi ìṣọ̀tẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀;

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →