YOR Job Chương 27

Job 27

YOR · So sánh · Âm thanh

1Pẹ̀lúpẹ̀lú Jobu sì tún sọkún ọ̀rọ̀ òwe rẹ̀, ó sì wí pé, 2“Bí Ọlọ́run ti ń bẹ, ẹni tí ó gba ìdájọ́ mi lọ, 3níwọ́n ìgbà tí ẹ̀mí mi ń bẹ nínú mi, 4Ètè mi kì yóò sọ̀rọ̀ èké, 5Kí a má rí i pé èmi ń dá yín láre; 6Òdodo mi ni èmi dìímú ṣinṣin, èmi kì yóò sì jọ̀wọ́ rẹ̀ lọ́wọ́; 7“Kí ọ̀tá mi kí ó dàbí ènìyàn búburú, 8Nítorí kí ni ìrètí àgàbàgebè, 9Ọlọ́run yóò ha gbọ́ àdúrà rẹ̀, 10Òun ha le ní inú dídùn sí Olódùmarè? 11“Èmi ó kọ́ yín ní ẹ̀kọ́ ní ti ọwọ́ Ọlọ́run: 12Kíyèsi i, gbogbo yín ni ó ti rí i; 13“Ẹ̀yin ni ìpín ènìyàn búburú lọ́dọ̀ Ọlọ́run, 14Bí àwọn ọmọ rẹ bá di púpọ̀, fún idà ni; 15Àwọn tí ó kù nínú tirẹ̀ ni a ó sìnkú nínú àjàkálẹ̀-ààrùn: 16Bí ó tilẹ̀ kó fàdákà jọ bí erùpẹ̀, 17àwọn ohun tí ó tò jọ àwọn olóòtítọ́ ni yóò lò ó; 18Òun kọ́ ilé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí kòkòrò aṣọ, 19Ọlọ́rọ̀ yóò dùbúlẹ̀, ṣùgbọ́n òun kì yóò túnṣe bẹ́ẹ̀ mọ́, 20Ẹ̀rù ńlá bà á bí omi ṣíṣàn; 21Ẹ̀fúùfù ìlà-oòrùn gbé e lọ, òun sì lọ; 22Nítorí pé Olódùmarè yóò kọlù ú, kì yóò sì dá sí; 23Àwọn ènìyàn yóò sì ṣápẹ́ sí i lórí,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →