YOR Job Chương 11

Job 11

YOR · So sánh · Âm thanh

1Ìgbà náà ni Sofari, ará Naama, dáhùn, ó sì wí pé, 2“A ha lè ṣe kí a máa dáhùn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rọ̀? 3Ṣé àmọ̀tán rẹ le mú ènìyàn pa ẹnu wọn mọ́ bí? 4Ìwọ sá à ti wí fún Ọlọ́run pé, ‘Ìṣe mi jẹ́ aláìléérí, 5Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ìbá jẹ́ sọ̀rọ̀, 6kí ó sì fi àṣírí ọgbọ́n hàn ọ́ pé, ó pọ̀ ju òye ènìyàn lọ, 7“Ìwọ ha le ṣe àwárí ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run bí? 8Ó ga ju àwọn ọ̀run lọ; kí ni ìwọ le è ṣe? 9Ìwọ̀n rẹ̀ gùn ju ayé lọ, 10“Bí òun bá rékọjá, tí ó sì sé ọnà 11Òun sá à mọ ẹlẹ́tàn ènìyàn; 12Ṣùgbọ́n òmùgọ̀ ènìyàn ki yóò di ọlọ́gbọ́n 13“Bí ìwọ bá fi ọkàn rẹ fún un, 14bí ìwọ bá gbé ẹ̀ṣẹ̀ tí ń bẹ ní ọwọ́ rẹ jù sọnù 15nígbà náà ni ìwọ ó gbé ojú rẹ sókè láìní àbàwọ́n, 16Nítorí pé ìwọ ó gbàgbé ìṣòro rẹ; 17Ọjọ́ ayé rẹ yóò sì mọ́lẹ̀ ju ọ̀sán gangan lọ, 18Ìwọ ó sì wà láìléwu, nítorí pé ìrètí wà; 19Ìwọ ó sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú, kì yóò sì sí ẹni tí yóò dẹ́rùbà ọ́, 20Ṣùgbọ́n ojú ìkà ènìyàn yóò mófo;

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →