YOR Job Chương 13

Job 13

YOR · So sánh · Âm thanh

1Wò ó, ojú mi ti rí gbogbo èyí rí, 2Ohun tí ẹ̀yin mọ̀, èmi mọ̀ pẹ̀lú, 3Nítòótọ́ èmi ó bá Olódùmarè sọ̀rọ̀, 4Ẹ̀yin fi irọ́ bá mi sọ̀rọ̀, 5Háà! ẹ̀yin kì bá kúkú dákẹ́! 6Ẹ gbọ́ àwíyé mi nísinsin yìí; 7Ẹ̀yin fẹ́ sọ ìsọkúsọ fún Ọlọ́run? 8Ẹ̀yin fẹ́ ṣe ojúsàájú rẹ̀? 9Ó ha dára to tí yóò hú àṣírí yín síta, 10Yóò máa bá yín wí nítòótọ́, 11Ìwà ọlá rẹ̀ kì yóò bà yín lẹ́rù bí? 12Àwọn òwe yín dàbí eérú, 13“Ẹ pa ẹnu yín mọ́ kúrò lára mi, kí èmi kí ó lè sọ̀rọ̀, 14Ǹjẹ́ nítorí kí ni èmi ṣe ń fi eyín mi bu ẹran-ara mi jẹ, 15Bí ó tilẹ̀ pa mí, síbẹ̀ èmi ó máa gbẹ́kẹ̀lé e, 16Èyí ni yóò sì ṣe ìgbàlà mi, 17Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu mi ní ìfarabalẹ̀, 18Wò ó nísinsin yìí, èmi ti mura ọ̀ràn mi sílẹ̀; 19Ta ni òun ti yóò bá mi ṣàròyé? 20“Ṣùgbọ́n, má ṣe ṣe ohun méjì yìí sí mi, 21Fa ọwọ́ rẹ sẹ́yìn kúrò lára mi, 22Nígbà náà ni kí ìwọ kí ó pè, èmi o sì dáhùn, 23Mélòó ní àìṣedéédéé àti ẹ̀ṣẹ̀ mi? 24Nítorí kí ni ìwọ ṣe pa ojú rẹ mọ́, 25Ìwọ ó fa ewé ti afẹ́fẹ́ ń fẹ́ síyìn-ín sọ́hùn-ún ya bi? 26Nítorí pé ìwọ kọ̀wé ohun kíkorò sí mi, 27Ìwọ kàn àbà mọ́ mi lẹ́sẹ̀ pẹ̀lú, 28“Bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn ń ṣègbé bí ohun ìdíbàjẹ́,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →