YOR Job Chương 33

Job 33

YOR · So sánh · Âm thanh

1Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ, 2Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi, 3Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi, 4Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi, 5Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn, 6kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà; 7Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ; 8“Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi, 9‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi; 10Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi; 11Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà; 12“Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà! 13Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé, 14Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan, 15Nínú àlá, ní ojúran òru, 16nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn, 17kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀; 18Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú, 19“A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀; 20bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ, 21Ẹran-ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè rí i mọ́ 22Àní, ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ isà òkú, 23Bí angẹli kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀, 24nígbà náà ni ó ṣe oore-ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé, 25Ara rẹ̀ yóò sì di ọ̀tun bí i ti ọmọ kékeré, 26Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì ṣe ojúrere rẹ̀, 27Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé, 28Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò, 29“Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run 30láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú, 31“Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi; 32Bí ìwọ bá sì ní ohun wí, dá mi lóhùn; 33Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi;

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →