YOR Psalm Розділ 25

Psalm 25

1Olúwa, 2Ọlọ́run, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ; 3Ẹni tí ó dúró tì ọ́ 4Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, Olúwa, 5ṣe amọ̀nà mi nínú òtítọ́ ọ̀ rẹ, kí o sì kọ́ mi, 6Rántí, Olúwa àánú àti ìfẹ́ ẹ̀ rẹ̀ ńlá, 7Má ṣe rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ìgbà èwe mi Olúwa. 8Rere àti ẹni ìdúró ṣinṣin ní Olúwa: 9Ó ṣe amọ̀nà àwọn onírẹ̀lẹ̀ ni ohun tí ó dára, 10Gbogbo ipa ọ̀nà Olúwa ni ìfẹ́ àti òdodo tí ó dúró ṣinṣin, 11Nítorí orúkọ rẹ, Olúwa, 12Àwọn wo ni ó bẹ̀rù Olúwa? 13Wọn yóò lo ọjọ́ wọn nínú àlàáfíà, 14Olúwa fi ọkàn tán, àwọn tí o bẹ̀rù u rẹ̀; 15Ojú mi gbé sókè sọ́dọ̀ Olúwa, 16Yípadà sí mi, kí o sì ṣe oore fún mi; 17Tì mí lẹ́yìn kúrò nínú ìpọ́njú àyà mi; 18Kíyèsi ìjìyà àti wàhálà mi, 19Kíyèsi ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀tá mi, 20Pa ọkàn mi mọ́, kí o sì gbà mí sílẹ̀; 21Jẹ́ kí òtítọ́ inú àti ìdúró ṣinṣin kí ó pa mí mọ́; 22Ra Israẹli padà, Ìwọ Ọlọ́run,

Щоденний ліміт досягнутий

Оновіть свій план, щоб продовжити використання можливостей ШІ з вищими щоденними лімітами.

Порівняти всі тарифи →