YOR Psalm Розділ 125

Psalm 125

1Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò dàbí òkè Sioni, 2Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká, Olúwa yí ènìyàn ká 3Nítorí tí ọ̀pá àwọn ènìyàn búburú 4Olúwa ṣe rere fún àwọn ẹni rere, 5Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; Olúwa yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.

Щоденний ліміт досягнутий

Оновіть свій план, щоб продовжити використання можливостей ШІ з вищими щоденними лімітами.

Порівняти всі тарифи →