YOR Psalm Розділ 22

Psalm 22

1lọ́run mi, Ọlọ́run mi, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mí sílẹ̀? 2Ọlọ́run mi, ní ọ̀sán gangan ni mo kígbe, ṣùgbọ́n ìwọ kò dá mi ní ohùn: 3Ṣùgbọ́n síbẹ̀ ẹni mímọ́ ni Ìwọ; 4Àwọn baba ńlá wa ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú rẹ; 5Ìwọ ni wọ́n sun ẹkún sí, wọ́n sì ní ìgbàlà; 6Ṣùgbọ́n kòkòrò ní mo jẹ́, kì í sì í ṣe ènìyàn; 7Gbogbo àwọn tí ó rí mí fi mí ṣe ẹlẹ́yà; 8“Ó gbẹ́kẹ̀ rẹ̀ lé Olúwa; Olúwa gbà á là. 9Síbẹ̀ ìwọ ni ó ti mú mi wá láti inú; 10Ìwọ ni a fi mí lé lọ́wọ́ láti inú ìyá mi wá, 11Má ṣe jìnnà sí mi, 12Ọ̀pọ̀ akọ màlúù yí mi ká; 13Wọ́n ya ẹnu wọn sì mi bí i kìnnìún tí ń dọdẹ kiri, 14A dà mí jáde gẹ́gẹ́ bí omi, 15Agbára mí ti gbẹ bí àpáàdì, 16Àwọn ajá yí mi ká; 17Mo lè ka gbogbo àwọn egungun mi; 18Wọ́n pín aṣọ mi láàrín ara wọn 19Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, má ṣe jìnnà sí mi. 20Gba ọkàn mi sílẹ̀ lọ́wọ́ idà, 21Gba ọkàn mi sílẹ̀ lọ́wọ́ kìnnìún; 22Èmi yóò kéde orúkọ rẹ láàrín arákùnrin àti arábìnrin mi; 23Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù Olúwa, ẹ yìn ín! 24Nítorí pé òun kò ṣátá, bẹ́ẹ̀ ni kò sì kórìíra 25Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìyìn mi yóò ti wá nínú àjọ ńlá; 26tálákà yóò jẹ yóò sì yó; Olúwa yóò yin 27Gbogbo òpin ayé ni yóò rántí Olúwa, 28nítorí ìjọba ni ti Olúwa. 29Bẹ́ẹ̀ náà ni gbogbo àwọn olówó ayé wọn yóò ṣe àsè, wọn yóò sì sìn; 30Irú-ọmọ rẹ̀ yóò sìn ín; Olúwa. 31Wọn yóò polongo òdodo rẹ̀

Щоденний ліміт досягнутий

Оновіть свій план, щоб продовжити використання можливостей ШІ з вищими щоденними лімітами.

Порівняти всі тарифи →