Yeşaya 55
1“Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òǹgbẹ ń gbẹ, 2Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrà 3Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi; 4Kíyèsi i, mo ti fi òun ṣe ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn, 5Lóòtítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀ Olúwa Ọlọ́run rẹ 6Ẹ wá Olúwa nígbà tí ẹ lè rí i; 7Jẹ́ kí ìkà kí ó kọ ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀ Olúwa, Òun yóò sì ṣàánú fún un, 8“Nítorí èrò mi kì í ṣe èrò yín, Olúwa wí. 9“Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ, 10Gẹ́gẹ́ bí òjò àti yìnyín 11bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá; 12Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀ 13Dípò igi ẹ̀gún ni igi junifa yóò máa dàgbà, Olúwa,