Yeşaya 40
1Ẹ tù ú nínú, ẹ tu ènìyàn mi nínú, 2Sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ fún Jerusalẹmu Olúwa 3Ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù: Olúwa ṣe, 4Gbogbo àfonífojì ni a ó gbé sókè, 5Ògo Olúwa yóò sì di mí mọ̀, Olúwa ni ó ti sọ ọ́.” 6Ohùn kan wí pé, “Kígbe sókè.” 7Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀, Olúwa ń fẹ́ lù wọ́n. 8Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀, 9Ìwọ tí o mú ìyìn ayọ̀ wá sí Sioni, 10Wò ó, Olúwa Olódùmarè náà ń bọ̀ wá pẹ̀lú agbára, 11Ó ń tọ́ àwọn agbo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn: 12Ta ni ó tiwọn omi nínú kòtò ọwọ́ rẹ̀, 13Ta ni ó ti mọ ọkàn Olúwa, 14Ta ni Olúwa ké sí kí ó là á lọ́yẹ 15Nítòótọ́ àwọn orílẹ̀-èdè dàbí i ẹ̀kún omi nínú garawa; 16Lebanoni kò tó fún pẹpẹ iná, 17Níwájú rẹ̀ ni gbogbo orílẹ̀-èdè dàbí ohun tí kò sí; 18Ta ni nígbà náà tí ìwọ yóò fi Ọlọ́run wé? 19Ní ti ère, oníṣọ̀nà ni ó dà á, 20Ọkùnrin kan tí ó tálákà jù kí ó lè mú 21Ǹjẹ́ o kò tí ì mọ̀ 22Òun jókòó lórí ìtẹ́ ní òkè òbírí ilẹ̀ ayé, 23Ó sọ àwọn ọmọ ọba di asán 24Gẹ́rẹ́ tí a ti gbìn wọ́n, 25“Ta ni ẹ ó fi mi wé? 26Gbé ojú rẹ sókè kí o sì wo àwọn ọ̀run. 27Èéṣe tí o fi sọ, ìwọ Jakọbu? Olúwa; 28Ìwọ kò tí ì mọ̀? Olúwa òun ni Ọlọ́run ayérayé, 29Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀ 30Àní, ó ń rẹ̀ wọ́n àwọn ọ̀dọ́, wọ́n ń rẹ̀wẹ̀sì, 31ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa