Yeşaya 27
1Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò fi idà rẹ̀ jẹ ni ní yà 2Ní ọjọ́ náà, 3Èmi Olúwa ń bojútó o, 4Inú kò bí mi. 5Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jẹ́ kí wọn wá sọ́dọ̀ mi fún ààbò; 6Ní ọjọ́ iwájú Jakọbu yóò ta gbòǹgbò, 7Ǹjẹ́ Olúwa ti lù ú 8Nípa ogun jíjà àti ìjìyà ti o le ni ó 9Nítorí èyí báyìí ni ètùtù yóò ṣe wà 10Ìlú olódi náà ti dahoro, 11Nígbà tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ bá rọ, a ó ya wọn dànù 12Ní ọjọ́ náà Olúwa yóò sì kó oore láti ìṣàn omi odo Eufurate wá títí dé Wadi ti Ejibiti, àti ìwọ, ìwọ ọmọ Israẹli, ni a ó kójọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan. 13Àti ní ọjọ́ náà, a ó fun fèrè ńlá kan. Gbogbo àwọn tí ń ṣègbé lọ ní Asiria àti àwọn tí ń ṣe àtìpó ní Ejibiti yóò wá sin Olúwa ní òkè mímọ́ ní Jerusalẹmu.