YOR Psalm Sura 80

Psalm 80

YOR · Linganisha · Sauti

1Gbọ́ tiwa, ìwọ olùṣọ́-àgùntàn Israẹli; 2níwájú Efraimu, Benjamini àti Manase. 3Mú wa padà bọ̀ sípò, ìwọ Ọlọ́run; 4Olúwa Ọlọ́run alágbára, 5Ìwọ ti fi oúnjẹ bọ́ wọn 6Ìwọ sọ wá di ẹlẹ́yà fún àwọn aládùúgbò wa, 7Tún wa yípadà, ìwọ, Ọlọ́run alágbára; 8Ìwọ mú àjàrà jáde láti Ejibiti; 9Ìwọ ṣí ààyè sílẹ̀ fún un, 10A bò àwọn òkè mọ́lẹ̀ òkè pẹ̀lú òjìji rẹ̀, 11O yọ ẹ̀ka rẹ̀ sínú Òkun, 12Èéṣe tí ìwọ fi wó odi rẹ̀ 13Ìmàdò láti inú igbó ń bá a jẹ́ 14Yípadà sí wa, àwa ń bẹ̀ ọ́, Ọlọ́run alágbára! 15gbòǹgbò èyí tí ọwọ́ ọ̀tún rẹ ti gbìn, 16A gé àjàrà rẹ lulẹ̀, a ti fi iná sun ún; 17Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó wà lára ọkùnrin tí ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, 18Nígbà náà àwa kí yóò yípadà kúrò lọ́dọ̀ rẹ; 19Tún wa yípadà, Olúwa Ọlọ́run alágbára;

Kikomo cha Kila Siku Kimefikia

Boresha mpango wako ili kuendelea na matumizi ya vipengele vya AI na mipango ya juu ya kila siku.

Linganisha mipango yote →