YOR Psalm Sura 58

Psalm 58

YOR · Linganisha · Sauti

1̀yin ha ń sọ òdodo nítòótọ́ 2Bẹ́ẹ̀ kọ́, nínú ọkàn yín ẹ̀yìn ń gbèrò àìṣòdodo, 3Ní inú ìyá wọn wá ni ènìyàn búburú tí ṣìnà, 4Oró wọn dàbí oró ejò, 5tí kò ní gbọ́ ìpè àwọn atunilójú, 6Ká eyín ẹnu wọn, Ọlọ́run; Olúwa. 7Jẹ́ kí wọn parẹ́ bí omi tó ń sàn lọ; 8Jẹ́ kí wọn rí bí ìgbín tí rẹ̀ dànù tí ó sì ṣègbé 9Kí ìkòkò yín kí ó tó mọ ìgbóná ẹ̀gún; 10Olódodo yóò yọ̀ nígbà a bá ń gbẹ̀san wọn, 11Àwọn ènìyàn yóò wí pé,

Kikomo cha Kila Siku Kimefikia

Boresha mpango wako ili kuendelea na matumizi ya vipengele vya AI na mipango ya juu ya kila siku.

Linganisha mipango yote →