YOR Psalm Sura 38

Psalm 38

YOR · Linganisha · Sauti

1Olúwa, má ṣe bá mi wí nínú ìbínú rẹ, 2Nítorí tí ọfà rẹ kàn mọ́ mi ṣinṣin, 3Kò sí ibi yíyè ní ara à mi, nítorí ìbínú rẹ; 4Nítorí àìṣedéédéé mi ti borí mi mọ́lẹ̀; 5Ọgbẹ́ mi ń rùn ó sì díbàjẹ́ 6Èmi ń jòwèrè, orí mi tẹ̀ ba gidigidi 7Nítorí ẹ̀gbẹ́ mi kún fún ìgbóná tí ń jóni 8Ara mi hù, a sì wó mi jẹ́gẹjẹ̀gẹ; 9Olúwa, gbogbo ìfẹ́ mi ń bẹ níwájú rẹ; 10Àyà mi ń mí hẹlẹ, agbára mi yẹ̀ mí sílẹ̀; 11Àwọn ọ̀rẹ́ mi àti àwọn ẹlẹgbẹ́ mi dúró lókèèrè réré kúrò níbi ìpọ́njú mi, 12Àwọn tí n wá ẹ̀mí mi dẹ okùn sílẹ̀ fún mi; 13Ṣùgbọ́n mo dàbí adití odi, èmi kò gbọ́ ọ̀rọ̀; 14Nítòótọ́, mo rí bí ọkùnrin tí kò gbọ́rọ̀, 15Ṣùgbọ́n sí ọ Olúwa, ìwọ ni mo dúró dè; 16Nítorí tí mo gbàdúrà, “Gbóhùn mi, kí wọn má ba à yọ̀ mí; 17Nítorí tí mo ti ṣetán láti ṣubú, 18Mo jẹ́wọ́ ìrékọjá mi; 19Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí pàtàkì, wọ́n lágbára púpọ̀, 20Àwọn tí wọn ń fi ibi san rere fún mi 21Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, ìwọ Olúwa! 22Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa, Olùgbàlà mi.

Kikomo cha Kila Siku Kimefikia

Boresha mpango wako ili kuendelea na matumizi ya vipengele vya AI na mipango ya juu ya kila siku.

Linganisha mipango yote →