Psaltaren 9
1Èmi ó yìn ọ́, Olúwa, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi; 2Inú mi yóò dùn, èmi yóò sì yọ̀ nínú rẹ; 3Àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà; 4Nítorí ìwọ ti di òtítọ́ àti ọ̀ràn mi mú; 5Ìwọ ti bá orílẹ̀-èdè wí, Ìwọ sì ti pa ẹni búburú run; 6Ìparun àìlópin ti borí àwọn ọ̀tá, 7Olúwa jẹ ọba títí láé; 8Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ ayé ní òdodo; 9Olúwa ni ààbò fún àwọn tí a ni lára, 10Àwọn tí ó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀lé ọ, Olúwa, kò kọ àwọn tó ń wá a sílẹ̀. 11Kọ orin ìyìn sí Olúwa, tí o ń jẹ ọba ní Sioni; 12Nítorí ẹni tí ó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ rántí; 13Olúwa, wo bí àwọn ọ̀tá ṣe ń ṣe inúnibíni sí mi! 14kí èmi kí ó lè sọ ti ìyìn rẹ 15Àwọn orílẹ̀-èdè ti jì sí kòtò tí wọn ti gbẹ́; 16A mọ Olúwa nípa òdodo rẹ̀; 17Àwọn ènìyàn búburú ni a ó dà sí isà òkú, 18Ṣùgbọ́n àwọn aláìní ni a kò ní gbàgbé láéláé, 19Dìde, Olúwa, má ṣe jẹ́ kí ènìyàn borí; 20Lù wọ́n pẹ̀lú ìpayà, Olúwa; Sela.