YOR Psaltaren Kapitel 48

Psaltaren 48

YOR · Jämför · Ljud

1ni ńlá ní Olúwa, tí ó sì yẹ láti máa yìn 2Ó dára nínú ipò ìtẹ́ rẹ̀, 3Ọlọ́run wà nínú ààbò ààfin rẹ̀; 4Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀, 5Wọn rí i, bẹ́ẹ̀ ni ẹnu sì yà wọ́n, 6Ẹ̀rù sì bà wọ́n níbẹ̀, 7Ìwọ bà wọ́n jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọkọ̀ orí omi Tarṣiṣi, 8Gẹ́gẹ́ bí a ṣe gbọ́, Olúwa àwọn ọmọ-ogun Sela. 9Láàrín tẹmpili rẹ, Ọlọ́run, 10Gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ Ọlọ́run, 11Jẹ́ kí òkè Sioni kí ó yọ̀ 12Rìn Sioni kiri lọ yíká rẹ̀, 13Kíyèsi odi rẹ̀, 14Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé,

Daglig gräns nådd

Uppgradera din plan för att fortsätta använda AI-funktioner med högre dagliga gränser.

Jämför alla planer →