Psaltaren 88
1Olúwa, Ọlọ́run tí ó gbà mí là, 2Jẹ́ kí àdúrà mi kí ó wá sí iwájú rẹ; 3Nítorí ọkàn mi kún fún ìpọ́njú 4A kà mí mọ́ àwọn tí wọ́n lọ sí ọ̀gbun ilẹ̀ 5A yà mí sọ́tọ̀ pẹ̀lú àwọn òkú 6Ìwọ tí ó fi mí sí kòtò jíjìn, 7Ìbínú rẹ ṣubú lé mi gidigidi; 8Ìwọ tí gba ọ̀rẹ́ mi tí ó súnmọ́ mi kúrò lọ́wọ́ mi 9ojú mi káàánú nítorí ìpọ́njú. Olúwa, ní gbogbo ọjọ́; 10Ìwọ ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ hàn fún òkú bi? 11A ó ha fi ìṣeun ìfẹ́ rẹ hàn ní ibojì bí, 12A ha lè mọ iṣẹ́ ìyanu rẹ ní òkùnkùn bí 13Ṣùgbọ́n mo kígbe sí ọ fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa; 14Olúwa, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mí 15Láti ìgbà èwe mi, ìṣẹ́ ń ṣẹ́ mi, 16Ìbínú rẹ ti kọjá lára mi; 17Ní gbogbo ọjọ́ ni wọn yí mi ká bí ìkún omi; 18Ìwọ ti mú ọ̀rẹ́ àti olùfẹ́ mi kúrò lọ́dọ̀ mi;