YOR Псалтирь Глава 49

Псалтирь 49

1 gbọ́ èyí, gbogbo ènìyàn! 2Àti ẹni tí ó ga àti ẹni tí ó kéré 3Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ọgbọ́n, 4èmi yóò dẹ etí mi sílẹ̀ sí òwe, 5Èéṣe ti èmi yóò bẹ̀rù nígbà tí ọjọ́ ibi dé? 6àwọn tí o gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọn, 7Kò sí ọkùnrin tí ó lè ra ẹ̀mí ẹnìkejì rẹ̀ 8Nítorí ìràpadà fún ẹni jẹ́ iyebíye 9ní ti kí ó máa wà títí ayé 10Nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn rí ọkùnrin ọlọ́gbọ́n tí ó kú, 11Ibojì wọn ni yóò jẹ́ ilé wọn láéláé, 12Ṣùgbọ́n ọkùnrin tí o wà nínú ọlá kò dúró pẹ́ 13Èyí ni òtítọ́ àwọn ènìyàn tí ó Sela. 14Gẹ́gẹ́ bí àgùntàn ni a tẹ́ wọn sínú isà òkú 15Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ra ọkàn mi padà 16Má ṣe bẹ̀rù nígbà tí ẹnìkan bá di ọlọ́rọ̀. 17Nítorí kì yóò mú ohun kan lọ nígbà tí ó bá kú, 18Nígbà tí ó wà láyé, ó súre fún ọkàn ara rẹ̀. 19Òun yóò lọ sí ọ̀dọ̀ ìran àwọn baba rẹ̀ 20Ọkùnrin tí ó ní ọlá tí kò ní òye dàbí ẹranko tí ó ṣègbé.

Дневной лимит достигнут

Обновите свой тариф, чтобы продолжить использовать функции ИИ с более высокими дневными лимитами.

Сравнить все тарифы →