Псалтирь 141
1Olúwa, èmi ké pè ọ́; yára wá sí ọ̀dọ̀ mi. 2Jẹ́ kí àdúrà mi ó wá sí iwájú rẹ bí ẹbọ tùràrí 3Fi ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ ẹnu mi, Olúwa: 4Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi, 5Jẹ́ kí olódodo lù mí, ìṣeun ni ó jẹ́: 6A ó ju àwọn alákòóso sílẹ̀ láti bẹ̀bẹ̀ òkúta, 7Wọn yóò wí pé, “Bí ẹni tí ó la aporo sórí ilẹ̀, 8Ṣùgbọ́n ojú mi ń bẹ lára rẹ, Olúwa Olódùmarè; 9Pa mí mọ́ kúrò nínú okùn tí wọn ti dẹ sílẹ̀ fún mi, 10Jẹ́ kí àwọn ẹni búburú ṣubú sínú àwọ̀n ara wọn,