YOR Псалтирь Глава 147

Псалтирь 147

1 fi ìyìn fún Olúwa. 2Olúwa kọ́ Jerusalẹmu; 3Ó wo àwọn tí ọkàn wọ́n bàjẹ́ sàn 4Ó ka iye àwọn ìràwọ̀ 5Títóbi ni Olúwa wa ó sì pọ̀ ní agbára 6Olúwa wa pẹ̀lú àwọn onírẹ̀lẹ̀ 7Fi ọpẹ́ kọrin sí Olúwa 8Ó fi ìkùùkuu bo àwọ̀ sánmọ̀ 9Ó pèsè oúnjẹ fún àwọn ẹranko 10Òun kò ní inú dídùn nínú agbára ẹṣin, 11Olúwa ni ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, 12Yin Olúwa, ìwọ Jerusalẹmu; 13Nítorí tí ó ti mú ọ̀pá ìdábùú ibodè rẹ̀ lágbára, 14Òun jẹ́ kí àlàáfíà wà ní àwọn ẹnu ibodè rẹ̀, 15Òun sì rán àṣẹ rẹ̀ sí ayé 16Ó fi yìnyín fún ni bi irun àgùntàn 17Ó rọ òjò yìnyín rẹ̀ bí òkúta wẹ́wẹ́ 18Ó rán ọ̀rọ̀ rẹ̀ jáde ó sì mú wọn yọ̀ 19Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ di mí mọ̀ fún Jakọbu 20Òun kó tí ṣe irú èyí sí orílẹ̀-èdè kan rí, bí ó ṣe ti ìdájọ́ rẹ̀ Olúwa.

Дневной лимит достигнут

Обновите свой тариф, чтобы продолжить использовать функции ИИ с более высокими дневными лимитами.

Сравнить все тарифы →