Psalmów 34
1Èmi yóò máa fi ìbùkún fún Olúwa nígbà gbogbo; 2Ọkàn mí yóò máa ṣògo nínú Olúwa; 3Gbé Olúwa ga pẹ̀lú mi; 4Èmi wá Olúwa, ó sì dá mi lóhùn; 5Wọ́n wò ó, ìmọ́lẹ̀ sì mọ́ wọn; 6Ọkùnrin olùpọ́njú yí kígbe, Olúwa sì gbóhùn rẹ̀; 7Angẹli Olúwa yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká 8Tọ́ ọ wò kí o sì rí i wí pé Olúwa dára; 9Ẹ bẹ̀rù Olúwa, ẹ̀yin ènìyàn rẹ̀ mímọ́, 10Àwọn ọmọ kìnnìún a máa ṣe aláìní ebi a sì máa pa wọ́n; Olúwa kì yóò ṣe aláìní ohun tí ó dára. 11Wá, ẹ̀yin ọmọ mi, fi etí sí mi; Olúwa. 12Ta ni nínú yín tí ń fẹ́ ìyè, tí ó sì ń fẹ́ ọjọ́ púpọ̀; 13Pa ahọ́n rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ibi 14Yà kúrò nínú ibi kí o sì ṣe rere; 15Ojú Olúwa ń bẹ lára àwọn olódodo; 16Ojú Olúwa korò sí àwọn tí ń ṣe búburú; 17Nígbà tí olódodo bá ké fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa a máa gbọ́, a sì yọ wọ́n jáde láti inú gbogbo wàhálà wọn. 18Olúwa súnmọ́ etí ọ̀dọ̀ àwọn oníròbìnújẹ́ ọkàn; 19Ìpọ́njú àwọn olódodo pọ̀, Olúwa gbà wọ́n kúrò nínú gbogbo rẹ̀. 20Ó pa gbogbo egungun wọn mọ́; 21Ibi ni ó mú ikú ìkà wá, 22Olúwa ra ọkàn àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ padà;