Psalmów 139
1Olúwa, ìwọ tí wádìí mi, 2Ìwọ mọ̀ ìjókòó mi àti ìdìde mi, 3Ìwọ yí ipa ọ̀nà mi ká àti ìdùbúlẹ̀ mi, 4Nítorí tí kò sí ọ̀rọ̀ kan ní ahọ́n mi, Olúwa, ìwọ mọ̀ ọ́n pátápátá. 5Ìwọ sé mi mọ́ lẹ́yìn àti níwájú, 6Irú ìmọ̀ yìí jẹ ohun ìyanu fún mi jù; 7Níbo ní èmi yóò gbé lọ kúrò ni ọwọ́ ẹ̀mí rẹ? 8Bí èmi bá gòkè lọ sí ọ̀run, ìwọ wà níbẹ̀; 9Èmi ìbá mú ìyẹ́ apá òwúrọ̀, 10àní, níbẹ̀ náà ni ọwọ́ rẹ̀ yóò fà mí 11Bí mo bá wí pé, “Ǹjẹ́ kí òkùnkùn kí ó bò mí mọ́lẹ̀; 12Nítòótọ́ òkùnkùn kì í ṣú lọ́dọ̀ rẹ; 13Nítorí ìwọ ni ó dá ọkàn mi; 14Èmi yóò yìn ọ, nítorí tẹ̀rù tẹ̀rù àti tìyanu tìyanu ní a dá mi; 15Ẹ̀dá ara mi kò pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ rẹ, 16ojú rẹ ti rí ohun ara mi 17Ọlọ́run, èrò inú rẹ tí ṣe iyebíye tó fún mi, 18Èmi ìbá kà wọ́n, 19Ọlọ́run ìbá jẹ́ pa àwọn ènìyàn búburú nítòótọ́; 20Ẹni tí ń fi inú búburú sọ̀rọ̀ sí ọ, 21Olúwa, ǹjẹ́ èmi kò kórìíra àwọn tó kórìíra rẹ? 22Èmi kórìíra wọn ní àkótán; 23Ọlọ́run, wádìí mi, kí o sì mọ ọkàn mí; 24Kí ó sì wò ó bí ipa ọ̀nà búburú