Psalmów 17
1Gbọ́, Olúwa, ẹ̀bẹ̀ òtítọ́ mi; 2Kí ìdáláre mi wá láti ọ̀dọ̀ rẹ; 3Ìwọ ti dán àyà mi wò, 4Bí ó ṣe ti iṣẹ́ ènìyàn nípa ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ, 5Ìrìn mí ti jẹ mọ́ ọ̀nà rẹ; 6Èmi ké pè ọ́, Ọlọ́run, nítorí tí ìwọ yóò dá mi lóhùn 7Fi ìṣeun ìyanu ìfẹ́ ńlá rẹ hàn 8Pa mí mọ́ bí ẹyin ojú rẹ; 9lọ́wọ́ àwọn ènìyàn búburú tí ń fóròó mi, 10Wọ́n pa ọkàn aláìláàánú wọn mọ́, 11Wọ́n sì mú mi mọ́lẹ̀, wọ́n sì yí mi ká, 12Wọn dàbí i kìnnìún tí ebi ń pa fún ìjẹ, 13Dìde, Olúwa, dojúkọ wọ́n, rẹ̀ wọ́n sílẹ̀; 14Olúwa, nípa ọwọ́ rẹ, gbà mí kúrò lọ́wọ́ irú àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀, 15Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi yóò máa wo ojú rẹ ní òdodo;