YOR Mazmur Pasal 18

Mazmur 18

YOR · Bandingkan · Audio

1Mo fẹ́ ọ, Olúwa, agbára mi. 2Olúwa ni àpáta àti odi mi, àti olùgbàlà mi; 3Mo ké pe Olúwa, ẹni tí ìyìn yẹ fún, 4Ìrora ikú yí mi kà, 5Okùn isà òkú yí mi ká, 6Nínú ìpọ́njú mo ké pe Olúwa; Olúwa mi fún ìrànlọ́wọ́. 7Ayé wárìrì, ó sì mì tìtì, 8Èéfín ti ihò imú rẹ̀ jáde wá; 9Ó pín àwọn ọ̀run, Ó sì jáde wá; 10Ó gun orí kérúbù, ó sì fò; 11Ó fi òkùnkùn ṣe ibojì rẹ̀, ó fi ṣe ìbòrí yí ara rẹ̀ ká 12Nípa ìmọ́lẹ̀ iwájú rẹ̀, àwọsánmọ̀ ṣíṣú dudu rẹ kọjá lọ 13Olúwa sán àrá láti ọ̀run wá; 14Ó ta àwọn ọfà rẹ̀, ó sì tú àwọn ọ̀tá náà ká, 15A sì fi ìsàlẹ̀ àwọn òkun hàn, Olúwa, 16Ó sọ̀kalẹ̀ láti ibi gíga, ó sì dì mímú; 17Ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára, 18Wọ́n dojúkọ mí ní ọjọ́ ìpọ́njú mi; Olúwa ni alátìlẹ́yìn mi. 19Ó mú mi jáde wá sínú ibi ńlá; 20Olúwa ti hùwà sí mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi; 21Nítorí mo ti pa ọ̀nà Olúwa mọ́; 22Gbogbo òfin rẹ̀ ni ó wà níwájú mi; 23Mo ti jẹ́ aláìlẹ́bi níwájú rẹ̀; 24Olúwa san ẹ̀san fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi; 25Fún olóòtítọ́ ni ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ní olóòtítọ́, 26sí ọlọ́kàn mímọ́, ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ní ọlọ́kàn mímọ́, 27O pa onírẹ̀lẹ̀ mọ́, 28Ìwọ, Olúwa, jẹ́ kí fìtílà mi 29Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ rẹ̀, èmi sáré tọ ogun lọ; 30Bí ó ṣe ti Ọlọ́run mi, ọ̀nà rẹ̀ pé, Olúwa 31Nítorí ta ni ṣe Ọlọ́run bí kò ṣe Olúwa? Olúwa wa? 32Ọlọ́run ni ẹni tí ó fi agbára dì mí ní àmùrè 33Ó ṣe ẹsẹ̀ mi gẹ́gẹ́ bi ẹsẹ̀ abo àgbọ̀nrín; 34Ó kọ́ ọwọ́ mi ni ogun jíjà; 35Ìwọ fi asà ìṣẹ́gun rẹ̀ fún mi, 36Ìwọ sọ ìrìn ẹsẹ̀ mi di ńlá ní ìsàlẹ̀ mi, 37Èmi lépa àwọn ọ̀tá mi, èmi sì bá wọn 38Èmi sá wọn ní ọgbẹ́ tí wọn ko fi le è dìde; 39Nítorí ìwọ fi agbára dì mí ní àmùrè fún ogun náà; 40Ìwọ yí ẹ̀yìn àwọn ọ̀tá mí padà sí mi 41Wọ́n kígbe fún ìrànlọ́wọ́, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan tí ó gbà wọ́n, Olúwa, ṣùgbọ́n kò dá wọn lóhùn. 42Mo lù wọ́n gẹ́gẹ́ bí eruku níwájú afẹ́fẹ́; 43Ìwọ ti gbà mí lọ́wọ́ ìkọlù àwọn ènìyàn; 44ni wéré ti wọ́n gbọ́ ohùn mi, wọ́n pa àṣẹ mi mọ́; 45Àyà yóò pá àlejò; 46Olúwa wà láààyè! Olùbùkún ni àpáta mi! 47Òun ni Ọlọ́run tí ó ń gbẹ̀san mi, 48tí ó pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mí. 49Títí láéláé, èmi yóò máa yìn ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ Olúwa; 50Ó fún ọba rẹ̀ ni ìṣẹ́gun ńlá;

Batas Harian Tercapai

Tingkatkan paket Anda untuk terus menggunakan fitur AI dengan batas harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua paket →