Mazmur 14
1Aṣiwèrè wí nínú ọkàn rẹ̀ pé, 2Olúwa sì bojú wolẹ̀ láti ọ̀run wá 3Gbogbo wọn sì ti yípadà, gbogbo wọn sì ti díbàjẹ́; 4Ǹjẹ́ olùṣe búburú kò ha ní ìmọ̀? Olúwa? 5Wọ́n wà níbẹ̀, tí a bò mọ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀rù, 6Ẹ̀yin olùṣe búburú da èrò àwọn tálákà rú, Olúwa ni ààbò wọn. 7Ìgbàlà àwọn Israẹli yóò ti Sioni wá! Olúwa bá mú ìkólọ àwọn ènìyàn rẹ̀ padà,