Mazmur 102
1Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa, 2Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ kúrò lọ́dọ̀ mi 3Nítorí tí ọjọ́ mi run bí èéfín; 4Àyà mi lù, ó sì rọ bí i koríko; 5Nítorí ohùn ìkérora mi, 6Èmi dàbí ẹyẹ igún ní ijù: 7Èmi dìde; èmi dàbí ẹyẹ lórí ilé. 8Ní ọjọ́ gbogbo, àwọn ọ̀tá ológoṣẹ́ mi ń gàn mí; 9Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi sì da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omijé. 10Nítorí ìbínú ríru rẹ, nítorí ìwọ ti gbé mi sókè, ìwọ sì gbé mi ṣánlẹ̀. 11Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́ 12Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé; 13Ìwọ ó dìde ìwọ ó sì ṣàánú fún Sioni, 14Nítorí tí àwọn òkúta jẹ́ inú dídùn sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ; 15Àwọn kèfèrí yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa, 16Torí tí Olúwa yóò gbé Sioni ró, yóò farahàn nínú ògo rẹ̀. 17Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní; 18Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀, Olúwa: 19“Olúwa wo ilẹ̀ láti òkè mímọ́ rẹ̀ wá 20láti gbọ́ ìrora ará túbú, 21Kí a lè sọ orúkọ Olúwa ní Sioni 22Ní ìgbà tí a kó àwọn ènìyàn àti Olúwa. 23Ní ipa ọ̀nà mi, ó rẹ agbára mi sílẹ̀, 24Èmi sì wí pé: 25Ní ìbẹ̀rẹ̀ ní ìwọ fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀, 26Wọn yóò ṣègbé, wọn yóò parun, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà; 27Ṣùgbọ́n ìwọ wà digbí síbẹ̀, 28Àwọn ọmọ ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò dúró ní iwájú rẹ pẹ́;