YOR Yesaya Pasal 9

Yesaya 9

YOR · Bandingkan · Audio

1Síbẹ̀síbẹ̀, kò ní sí ìpòrúru kankan mọ́ fún àwọn tí ó wà nínú ìbànújẹ́. Nígbà kan rí ó rẹ ilẹ̀ Sebuluni sílẹ̀ àti ilẹ̀ Naftali pẹ̀lú, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ iwájú, yóò bu ọ̀wọ̀ fún Galili ti àwọn aláìkọlà, ní ọ̀nà Òkun, ní ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ Jordani. 2Àwọn ènìyàn tí ń rìn nínú òkùnkùn 3Ìwọ ti sọ orílẹ̀-èdè di ńlá; 4Nítorí gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí a ṣẹ́gun Midiani, 5Gbogbo bàtà jagunjagun tí a ti lò lójú ogun 6Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, 7Ní ti gbígbòòrò Ìjọba rẹ̀ àti àlàáfíà rẹ̀ ni kì yóò ní ìpẹ̀kun. Olúwa àwọn ọmọ-ogun Olúwa Sí Israẹli 8Olúwa ti dojú iṣẹ́ kan kọ Jakọbu; 9Gbogbo ènìyàn ni yóò sì mọ̀ ọ́n— 10Àwọn bíríkì ti wó lulẹ̀ 11Ṣùgbọ́n Olúwa fún àwọn ọ̀tá Resini ní agbára láti dojúkọ wọ́n 12Àwọn ará Aramu láti ìlà-oòrùn àti Filistini láti ìwọ̀-oòrùn. 13Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn náà kò tí ì yípadà Olúwa àwọn ọmọ-ogun. 14Nítorí náà ni Olúwa yóò ṣe ké àti orí àti ìrù 15àwọn àgbàgbà, àti àwọn gbajúmọ̀ ní orí, 16Àwọn tí ó ń tọ́ àwọn ènìyàn wọ̀nyí ṣì wọ́n lọ́nà, 17Nítorí náà, Olúwa kì yóò dunnú sí àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin 18Nítòótọ́ ìwà búburú ń jóni bí iná, 19Nípasẹ̀ ìbínú Olúwa àwọn ọmọ-ogun 20Ní apá ọ̀tún wọn yóò jẹrun, 21Manase yóò máa jẹ Efraimu, nígbà tí Efraimu yóò jẹ Manase

Batas Harian Tercapai

Tingkatkan paket Anda untuk terus menggunakan fitur AI dengan batas harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua paket →