Yesaya 56
1Èyí ni ohun ti Olúwa sọ: 2Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó ṣe èyí, 3Má ṣe jẹ́ kí àjèjì kan tí ó ti di ara rẹ̀ Olúwa sọ wí pé, Olúwa yóò yà mí sọ́tọ̀ kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.” 4Nítorí pé báyìí ni Olúwa wí: 5fún wọn ni Èmi yóò fún nínú tẹmpili àti àgbàlá rẹ̀ 6Àti àwọn àjèjì tí ó so ara wọn mọ́ Olúwa Olúwa 7àwọn wọ̀nyí ni èmi yóò mú wá òkè mímọ́ mi, 8Olúwa Olódùmarè sọ wí pé— 9Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin ẹranko inú pápá, 10Àwọn olùṣọ́ Israẹli fọ́jú, 11Wọ́n jẹ́ àwọn ajá tí ó kúndùn púpọ̀; 12Igbe ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ni wí pé, “Wá, fún mi ní ọtí wáìnì!