YOR Yesaya Pasal 48

Yesaya 48

YOR · Bandingkan · Audio

1Tẹ́tí sí èyí, ìwọ ilé e Jakọbu, Olúwa 2ìwọ tí ò ń pe ara rẹ ní ọmọ ìlú mímọ́ n nì Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀. 3Èmi sọ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn nǹkan ti tẹ́lẹ̀ lọ́jọ́ tó ti pẹ́, 4Nítorí mo mọ bí ẹ ti jẹ́ olórí kunkun tó; 5Nítorí náà mo ti sọ nǹkan wọ̀nyí fún ọ 6Ìwọ ti gbọ́ àwọn nǹkan wọ̀nyí; wo gbogbo wọn. 7A dá wọn ní àkókò yìí kì í ṣe láti ìgbà pípẹ́ 8Ìwọ a ha ti gbọ́ tàbí ó ti yé ọ bí 9Nítorí orúkọ ara mi, mo dáwọ́ ìbínú mi dúró; 10Wò ó, èmi ti tún ọ ṣe, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé 11Nítorí orúkọ mi, nítorí orúkọ mi, mo ṣe èyí. 12“Tẹ́tí sí mi, ìwọ Jakọbu 13Ọwọ́ mi pàápàá ni ó fi àwọn ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀, 14“Gbogbo yín, ẹ péjọ kí ẹ sì gbọ́. Olúwa ti fẹ́ ẹ, 15Èmi, àní Èmi ló ti sọ̀rọ̀; 16“Ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi kí ẹ sì dẹtí sí èyí: Olúwa Olódùmarè ni ó ti rán mi, 17Èyí ni ohun tí Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run rẹ, 18Bí ó bá ṣe pé ìwọ bá ti tẹ́tí sílẹ̀ sí àṣẹ mi, 19Àwọn ọmọ rẹ ìbá ti dàbí iyanrìn, 20Fi Babeli sílẹ̀, Olúwa ti dá ìránṣẹ́ rẹ̀ Jakọbu nídè.” 21Òrùngbẹ kò gbẹ wọ́n nígbà tí ó kó wọn 22“Kò sí àlàáfíà,” ni Olúwa wí,

Batas Harian Tercapai

Tingkatkan paket Anda untuk terus menggunakan fitur AI dengan batas harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua paket →