Izaija 59
1Lódodo ọwọ́ Olúwa kò kúrú láti gbàlà, 2Ṣùgbọ́n ẹ̀ṣẹ̀ yín ló ti yà yín kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run yín; 3Nítorí ọwọ́ yín di aláìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀, 4Kò sí ẹni tí ó béèrè fún ìdájọ́ òdodo; 5Wọn ń pa ẹ̀yin paramọ́lẹ̀ 6Òwú wọn kò wúlò fún aṣọ rírán; 7Ẹsẹ̀ wọn yára bọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀; 8Ọ̀nà àlàáfíà èyí ni wọn kò mọ̀; 9Nítorí èyí ni ẹ̀tọ́ fi jìnnà sí wa, 10Gẹ́gẹ́ bí afọ́jú à ń táràrà lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ògiri 11Gbogbo wa là ń ké bí i beari; 12Nítorí àwọn àṣìṣe wa pọ̀ níwájú rẹ, 13ọ̀tẹ̀ àti àrékérekè wa sí Olúwa, 14Nítorí èyí ni a ṣe lé ìdájọ́ òdodo sẹ́yìn, 15A kò rí òtítọ́ mọ́, Olúwa wò ó ọkàn rẹ̀ sì bàjẹ́ 16Òun rí i pé kò sí ẹnìkan, 17Ó gbé òdodo wọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàyà rẹ̀, 18Gẹ́gẹ́ bí ohun tí wọ́n ti ṣe, 19Láti ìwọ̀-oòrùn, àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa, Olúwa ń tì lọ. 20“Olùdáǹdè yóò wá sí Sioni, Olúwa wí. 21“Àti fún èmi, májẹ̀mú mi pẹ̀lú wọn nìyìí,” ni Olúwa wí, “Ẹ̀mí mi, tí ó wà nínú yín, àti ọ̀rọ̀ mi tí mo ti fi sí ẹnu yín, kì yóò kúrò lẹ́nu yín, tàbí lẹ́nu àwọn ọmọ yín, tàbí láti ẹnu àwọn ìrandíran wọn láti àkókò yìí lọ àti títí láéláé,” ni Olúwa wí.