Izaija 53
1Ta ni ó ti gba ìròyìn in wa gbọ́ Olúwa hàn fún? 2Òun dàgbàsókè níwájú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ irúgbìn, 3A kẹ́gàn rẹ̀ àwọn ènìyàn sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀, 4Lóòtítọ́ ó ti ru àìlera wa lọ 5Ṣùgbọ́n a sá a lọ́gbẹ́ nítorí àìṣedéédéé wa 6Gbogbo wa bí àgùntàn, ti ṣìnà lọ, Olúwa sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀ 7A jẹ ẹ́ ní yà, a sì pọ́n ọn lójú, 8Pẹ̀lú ìpọ́nlójú àti ìdánilẹ́jọ́ ni a mú un jáde lọ, 9A fún un ní ibojì pẹ̀lú àwọn ìkà, 10Síbẹ̀, ó wu Olúwa láti pa á lára Olúwa fi ayé rẹ̀ Olúwa ni yóò gbèrú ní ọwọ́ rẹ̀. 11Lẹ́yìn ìpọ́njú ẹ̀mí rẹ̀, 12Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńlá