YOR अय्यूब अध्याय 37

अय्यूब 37

1Àyà sì fò mi sí èyí pẹ̀lú, 2Fetísílẹ̀! Fetísílẹ̀, kí ẹ sì gbọ́ ìró ohùn rẹ̀, 3Ó ṣe ìlànà rẹ̀ ní ìsàlẹ̀ ọ̀run gbogbo, 4Lẹ́yìn mọ̀nàmọ́ná ohùn kan fọ̀ ramúramù; 5Ọlọ́run fi ohùn rẹ̀ sán àrá ní ọ̀nà ìyanu; 6Nítorí tí ó wí fún yìnyín pé, ‘Ìwọ rọ̀ sílẹ̀ ayé,’ 7Ó fi èdìdì di ọwọ́ gbogbo ènìyàn kí gbogbo wọn kí ó lè mọ iṣẹ́ rẹ̀, 8Nígbà náà ní àwọn ẹranko wọ inú ihò lọ, 9Láti ìhà gúúsù ni ìjì àjàyíká tí jáde wá, 10Nípa ẹ̀mí Ọlọ́run a fi ìdí omi fún ni, 11Pẹ̀lúpẹ̀lú ó fi omi púpọ̀ mú àwọsánmọ̀ wúwo, 12Àwọn wọ̀nyí yí káàkiri nípa ìlànà rẹ̀, 13Ó mú àwọsánmọ̀ wá, ìbá ṣe fún ìkìlọ̀, 14“Jobu, dẹtí sílẹ̀ sí èyí; 15Ṣe ìwọ mọ àkókò ìgbà tí Ọlọ́run ṣe wọ́n lọ́jọ̀, 16Ṣé ìwọ mọ ìgbà tí àwọsánmọ̀ í fò lọ, 17Ìwọ ẹni ti aṣọ rẹ̀ ti máa n gbóná, 18Ìwọ ha ba tẹ́ pẹpẹ ojú ọ̀run, tí ó dúró ṣinṣin, 19“Kọ́ wa ní èyí tí a lè wí fún un; 20A ó ha wí fún un pé, èmi fẹ́ sọ̀rọ̀? 21Síbẹ̀ nísinsin yìí ènìyàn kò rí 22Wúrà dídán ti inú ìhà àríwá jáde wá; 23Nípa ti Olódùmarè àwa kò le wádìí rẹ̀, ó rékọjá ní ipá; 24Nítorí náà ènìyàn ha máa bẹ̀rù rẹ̀,

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →