अय्यूब 41
1“Ǹjẹ́ ìwọ le è fi ìwọ̀ fa Lefitani jáde? 2Ìwọ lè fi okùn bọ̀ ọ́ ní í mú, 3Òun ha jẹ́ bẹ ẹ̀bẹ̀ fún àánú lọ́dọ̀ 4Òun ha bá ọ dá májẹ̀mú bí? 5Ìwọ ha lè ba sáré bí ẹni pé ẹyẹ ni, 6Ẹgbẹ́ àwọn apẹja yóò ha máa tà á bí? 7Ìwọ ha lè fi ọ̀kọ̀-irin gun awọ rẹ̀, 8Fi ọwọ́ rẹ lé e lára, 9Kíyèsi, ìgbìyànjú láti mú un ní asán; 10Kò sí ẹni aláyà lílé tí ó lè ru sókè. 11Ta ni ó kọ́kọ́ ṣe fún mi, tí èmi ìbá fi san án fún un? 12“Èmi kì yóò fi ẹ̀yà ara Lefitani, 13Ta ni yóò lè rídìí aṣọ àpáta rẹ̀? 14Ta ni ó lè ṣí ìlẹ̀kùn iwájú rẹ̀? 15Ìpẹ́ lílé ní ìgbéraga rẹ̀; 16Èkínní fi ara mọ́ èkejì tó bẹ́ẹ̀ 17Èkínní fi ara mọ́ èkejì rẹ̀; 18Nípa sí sin rẹ̀ ìmọ́lẹ̀ á mọ́, 19Láti ẹnu rẹ ni ọ̀wọ́-iná ti jáde wá, 20Láti ihò imú rẹ ni èéfín ti jáde wá, 21Èémí rẹ̀ tiná bọ ẹ̀yin iná, 22Ní ọrùn rẹ̀ ní agbára kù sí, 23Jabajaba ẹran rẹ̀ dìjọ pọ̀, 24Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta, 25Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù; 26Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà, 27Ó ká irin sí ibi koríko gbígbẹ 28Ọfà kò lè mú un sá; 29Ó ka ẹṣin sí bí àgékù ìdì koríko; 30Òkúta mímú ń bẹ nísàlẹ̀ abẹ́ rẹ̀, 31Ó mú ibú omi hó bí ìkòkò; 32Ó mú ipa ọ̀nà tan lẹ́yìn rẹ̀; 33Lórí ilẹ̀ ayé kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ̀, 34Ó bojú wo ohun gíga gbogbo,