YOR अय्यूब अध्याय 6

अय्यूब 6

1Jobu sì dáhùn ó si wí pé, 2“Háà! À bá lè wọ́n ìbìnújẹ́ mi nínú òsùwọ̀n, 3Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ìbá wúwo jú iyanrìn òkun lọ, 4Nítorí pé ọfà Olódùmarè wọ̀ mi nínú, 5Ǹjẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó á máa dún nígbà tí ó bá ní koríko, 6A ha lè jẹ ohun tí kò ní adùn ní àìní iyọ̀, 7Ohun ti ọ̀kan mi kọ̀ láti tọ́wò, 8“Háà! èmi ìbá lè rí ìbéèrè mi gbà; 9Àní Ọlọ́run ìbá jẹ́ pa mí run, 10Nígbà náà ní èmi ìbá ní ìtùnú síbẹ̀, 11“Kí ní agbára mi tí èmi ó fi retí? 12Agbára mi ha ṣe agbára òkúta bí? 13Ìrànlọ́wọ́ mi kò ha wà nínú mi: 14“Ẹni tí àyà rẹ̀ yọ́ dànù, ta ni a bá máa ṣàánú fún láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ rẹ̀ wá, 15Àwọn ará mi dàbí odò tí kò ṣe gbẹ́kẹ̀lé 16Tí ó dúdú nítorí omi dídì, 17Nígbàkígbà tí wọ́n bá gbóná wọn a sì yọ́ sàn lọ, 18Àwọn oníṣòwò yà kúrò ní ọ̀nà wọn, 19Ẹgbẹ́ oníṣòwò Tema ń wá omi, 20Wọ́n káàárẹ̀, nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lé e; 21Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ẹ̀yin dàbí wọn; 22Èmi ó ha wí pé, ‘Ẹ mú ohun fún mi wá, 23Tàbí, ẹ gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá ni, 24“Ẹ kọ́ mi, èmi ó sì pa ẹnu mi mọ́ 25Wò ó! Bí ọ̀rọ̀ òtítọ́ ti lágbára tó 26Ẹ̀yin ṣè bí ẹ tún ọ̀rọ̀ mi ṣe 27Àní ẹ̀yin ṣe gẹ́gẹ́ bí aláìní baba, 28“Nítorí náà, kí èyí kí ó tó fún yín. 29Èmi ń bẹ̀ yín, ẹ padà, kí ó má sì ṣe jásí ẹ̀ṣẹ̀; 30Àìṣedéédéé ha wà ní ahọ́n mi?

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →