अय्यूब 29
1Pẹ̀lúpẹ̀lú, Jobu sì tún tẹ̀síwájú nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, 2“Háà! ìbá ṣe pé èmi wà bí ìgbà oṣù tí ó kọjá, 3nígbà tí fìtílà rẹ tàn sí mi ní orí, 4Bí mo ti rí nígbà ọ̀dọ́ mi, 5nígbà tí Olódùmarè wà pẹ̀lú mi, 6nígbà tí èmi fi òrí-àmọ́ n wẹ ìṣísẹ̀ mi, 7“Nígbà tí mo jáde la àárín ìlú lọ sí ẹnu ibodè, 8nígbà náà ni àwọn ọmọkùnrin rí mi, 9àwọn ọmọ-aládé dákẹ́ ọ̀rọ̀ sísọ, 10Àwọn ọlọ́lá dákẹ́, 11Nígbà tí etí gbọ́, ó sì súre fún mi, 12nítorí mo gbà tálákà tí n fẹ́ ìrànlọ́wọ́, 13Ẹni tí ó ń kìlọ̀ súre fún mi, 14Èmi sì mú òdodo wọ̀ bí aṣọ, 15Mo ṣe ojú fún afọ́jú mo sì ṣe ẹsẹ̀ 16Mo ṣe baba fún tálákà; 17Mo sì ká eyín ẹ̀rẹ̀kẹ́ ènìyàn búburú, 18“Nígbà náà ni mo rò pé, ‘Èmi yóò kú nínú ilé mi, 19Gbòǹgbò mi yóò ta kan omi, 20Ògo mi yóò wà ní ọ̀tún ní ọ̀dọ̀ mi, 21“Èmi ni ènìyàn ń dẹtí sílẹ̀ sí, 22Lẹ́yìn ọ̀rọ̀ mi, wọn kò tún sọ̀rọ̀ mọ́; 23Wọn a sì dúró dè mí bí ẹni wí pé wọ́n dúró fún ọ̀wọ́ òjò; 24Èmi sì rẹ́rìn-ín sí wọn nígbà tí wọn kò bá gbà á gbọ́; 25Mo la ọ̀nà sílẹ̀ fún wọn, mo sì jókòó bí olóyè wọn.