अय्यूब 33
1“Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ, 2Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi, 3Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi, 4Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi, 5Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn, 6kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà; 7Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ; 8“Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi, 9‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi; 10Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi; 11Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà; 12“Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà! 13Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé, 14Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan, 15Nínú àlá, ní ojúran òru, 16nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn, 17kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀; 18Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú, 19“A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀; 20bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ, 21Ẹran-ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè rí i mọ́ 22Àní, ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ isà òkú, 23Bí angẹli kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀, 24nígbà náà ni ó ṣe oore-ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé, 25Ara rẹ̀ yóò sì di ọ̀tun bí i ti ọmọ kékeré, 26Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì ṣe ojúrere rẹ̀, 27Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé, 28Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò, 29“Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run 30láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú, 31“Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi; 32Bí ìwọ bá sì ní ohun wí, dá mi lóhùn; 33Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi;