YOR Ψαλμοί Κεφάλαιο 94

Ψαλμοί 94

1Olúwa Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san, 2Gbé ara rẹ sókè, ìwọ onídàájọ́ ayé; 3Báwo ní yóò ti pẹ́ tó, Olúwa 4Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga jáde; 5Wọ́n fọ́ àwọn ènìyàn rẹ túútúú, Olúwa: 6Wọ́n pa àwọn opó àti àlejò, 7Wọ́n sọ pé, “Olúwa kò rí i; 8Kíyèsi i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn; 9Ẹni tí ó gbin etí, ó lè ṣe aláìgbọ́ bí? 10Ẹni tí ń bá orílẹ̀-èdè wí, ṣé kò lè tọ́ ni ṣọ́nà bí? 11Olúwa mọ èrò inú ènìyàn; 12Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí Olúwa, 13Ìwọ gbà á kúrò nínú ọjọ́ ibi, 14Nítorí Olúwa kò ní kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀, 15Ìdájọ́ yóò padà sí òdodo, 16Ta ni yóò dìde fún mi 17Bí kò ṣe pé Olúwa fún mi ní ìrànlọ́wọ́, 18Nígbà tí mo sọ pé, “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀”, Olúwa, ìfẹ́ rẹ̀ ni ó tì mí lẹ́yìn. 19Nígbà tí àníyàn ńlá wà nínú mi, 20Ìjọba ìbàjẹ́ ha lè kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú rẹ 21Wọ́n kó ara wọn jọ sí olódodo 22Ṣùgbọ́n, Olúwa ti di odi alágbára mi, 23Òun yóò san ẹ̀san ibi wọn fún wọn Olúwa Ọlọ́run wa yóò pa wọ́n run.

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →