Ψαλμοί 145
1Èmi yóò gbé ọ ga, Ọlọ́run ọba mi; 2Ní ojoojúmọ́ èmi yóò yìn ọ́ 3Títóbi ni Olúwa. Òun sì ni ó yẹ láti fi ìyìn fún púpọ̀púpọ̀: 4Ìran kan yóò máa yin iṣẹ́ rẹ dé ìran mìíràn; 5Wọn yóò máa sọ ìyìn ọláńlá rẹ tí ó lógo, 6Wọn yóò sọ iṣẹ́ agbára rẹ tí ó ní ẹ̀rù 7Wọn yóò ṣe ìrántí ọ̀pọ̀lọpọ̀ 8Olóore-ọ̀fẹ́ ni Olúwa àti aláàánú 9Olúwa dára sí ẹni gbogbo; 10Gbogbo ohun tí ìwọ ti dá ni Olúwa; 11Wọn yóò sọ ògo ìjọba rẹ 12kí gbogbo ènìyàn le mọ iṣẹ́ agbára rẹ̀ 13Ìjọba rẹ ìjọba ayérayé ni, 14Olúwa mú gbogbo àwọn tí ó ṣubú ró 15Ojú gbogbo ènìyàn ń wò ọ́, 16Ìwọ ṣí ọwọ́ rẹ 17Olúwa jẹ́ olódodo ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀ 18Olúwa wà ní tòsí gbogbo àwọn tí ń ké pè é, 19Ó mú ìfẹ́ àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ṣẹ; 20Olúwa dá gbogbo àwọn tí ó ní ìfẹ́ sẹ sí 21Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ìyìn Olúwa.