YOR Ψαλμοί Κεφάλαιο 45

Ψαλμοί 45

1kàn mi mọ ọ̀rọ̀ rere 2Ìwọ yanjú ju àwọn ọmọ ènìyàn lọ: 3Gba idà rẹ mọ́ ìhà rẹ, ìwọ alágbára jùlọ 4Nínú ọláńlá rẹ, máa gẹṣin lọ ní àlàáfíà lórí òtítọ́, 5Jẹ́ kí ọfà mímú rẹ̀ dá ọkàn àwọn ọ̀tá ọba lu 6Ọlọ́run láé, àti láéláé ni ìtẹ́ rẹ, 7Ìwọ fẹ́ olódodo, ìwọ sì kórìíra ìwà búburú 8Gbogbo aṣọ rẹ̀ ni ó ń rùn pẹ̀lú òjìá àti aloe àti kasia; 9Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba 10Gbọ́ ìwọ ọmọbìnrin, ronú kí o sì dẹtí rẹ sí mi 11Bẹ́ẹ̀ ni ọba yóò fẹ́ ẹwà rẹ gidigidi 12Ọmọbìnrin ọba Tire yóò wá pẹ̀lú ẹ̀bùn 13Gbogbo ògo ni ti ọmọbìnrin ọba ní àárín ilé rẹ̀, 14Nínú aṣọ olówó iyebíye ni a mú un tọ́ ọba wá, 15Wọ́n sì mú un wá pẹ̀lú ayọ̀ àti inú dídùn 16Ọmọ rẹ̀ ni yóò gba ipò baba rẹ̀ 17Èmí yóò máa rántí orúkọ rẹ̀ ní ìran gbogbo,

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →