YOR Psalm Kapitel 77

Psalm 77

YOR · Sammenlign · Lyd

1Mó kígbe sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́; 2Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú, Olúwa; 3Èmi rántí rẹ, Ọlọ́run, Sela. 4Ìwọ kò fẹ́ kí èmi fi ojú ba oorun, 5Mo ronú nípa ọjọ́ ìgbàanì; 6mo rántí orin mi ní òru. 7“Olúwa yóò ha kọ̀ títí láé? 8Ṣe ìfẹ́ rẹ̀ àti àánú rẹ̀ ti kú lọ láéláé? 9Ọlọ́run ha gbàgbé láti máa ṣàánú? Sela. 10Èmi wí pé, “Èyí ní ẹ̀dùn ọkàn mi, 11Èmi ó rántí iṣẹ́ Olúwa: 12Èmi ṣàṣàrò lórí iṣẹ́ rẹ gbogbo, 13Ọlọ́run, ọ̀nà rẹ jẹ́ mímọ́. 14Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu; 15Pẹ̀lú ọwọ́ agbára rẹ ni ìwọ ra àwọn ènìyàn padà, Sela. 16Nígbà tí àwọn omi rí Ọlọ́run, 17Àwọn ojú ọ̀run tú omi sílẹ̀, 18Àrá rẹ̀ ni a gbọ́ nínú ìjì, 19Ipa rẹ̀ gba Òkun, ọ̀nà rẹ̀ ń bẹ nínú Òkun, 20Ó tọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →