YOR Psalm Kapitel 119

Psalm 119

YOR · Sammenlign · Lyd

1Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ọ̀nà wọn wà láìlẹ́ṣẹ̀, Olúwa. 2Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ń pa òfin rẹ̀ mọ́ 3Wọn kò ṣe ohun tí kò dára; 4Ìwọ ti la ìlànà rẹ̀ sílẹ̀ 5Ọ̀nà mi ìbá dúró ṣinṣin 6Nígbà náà, ojú kò ní tì mí 7Èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú ọkàn ìdúró ṣinṣin 8Èmi yóò gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ̀, 9Báwo ni àwọn ọ̀dọ́ yóò ti ṣe pa ọ̀nà rẹ̀ mọ́? 10Èmi wá ọ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi 11Èmi ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́ ní ọkàn mi 12Ìyìn ni fún Olúwa; 13Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò 14Èmi ń yọ̀ ní ọ̀nà ẹ̀rí rẹ, 15Èmi ń ṣe àṣàrò nínú ìlànà rẹ 16Inú mi dùn sí àṣẹ rẹ; 17Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ, èmi yóò sì wà láààyè; 18La ojú mi kí èmi lè ríran rí 19Àlejò ní èmi jẹ́ láyé, 20Ọkàn mi pòruurù pẹ̀lú ìfojúsọ́nà 21Ìwọ fi àwọn agbéraga bú, àwọn tí a fi gégùn ún 22Mú ẹ̀gàn àti àbùkù kúrò lára mi, 23Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn alákòóso kójọpọ̀, 24Òfin rẹ ni dídùn inú mi; 25Ọkàn mí lẹ̀ mọ́ erùpẹ̀; 26Èmi tún ọ̀nà mi ṣírò ìwọ sì dá mi lóhùn; 27Jẹ́ kí n mọ ẹ̀kọ́ ìlànà rẹ: 28Ọkàn mi ń ṣe àárẹ̀ pẹ̀lú ìbànújẹ́; 29Pa mí mọ́ kúrò nínú ọ̀nà ẹ̀tàn 30Èmi ti yan ọ̀nà òtítọ́ 31Èmi yára di òfin rẹ mú. Olúwa 32Èmi sáré ní ipa ọ̀nà àṣẹ rẹ, 33Kọ́ mi, Olúwa, láti tẹ̀lé àṣẹ rẹ; 34Fún mi ní òye, èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́ 35Fi ipa ọ̀nà àṣẹ rẹ hàn mí, 36Yí ọkàn mi padà sí òfin rẹ 37Yí ojú mi padà kúrò láti máa wo ohun asán: 38Mú ìlérí rẹ sẹ sí ìránṣẹ́ rẹ, 39Yí ẹ̀gàn mi padà tí mo bẹ̀rù 40Kíyèsi i, ọkàn mi ti fà sí ẹ̀kọ́ rẹ! 41Jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà wá bá mi, Olúwa, 42Nígbà náà ni èmi yóò dá 43Má ṣe gba ọ̀rọ̀ òtítọ́ láti ẹnu mi 44Èmi yóò máa gbọ́rọ̀ sí òfin rẹ nígbà gbogbo 45Èmi yóò máa rìn káàkiri ní òmìnira, 46Èmi yóò sọ̀rọ̀ òfin rẹ níwájú àwọn ọba 47nítorí èmi ní inú dídùn nínú àṣẹ rẹ 48Èmi gbé ọwọ́ mi sókè nítorí àṣẹ rẹ, èyí tí èmi fẹ́ràn, 49Rántí ọ̀rọ̀ rẹ sí ìránṣẹ́ rẹ, 50Ìtùnú mi nínú ìpọ́njú mi ni èyí: 51Àwọn agbéraga fi mí ṣe ẹlẹ́yà láì dádúró, 52Èmi rántí àwọn òfin rẹ ìgbàanì, Olúwa, 53Ìbínú dì mímú ṣinṣin nítorí àwọn ẹni búburú, 54Òfin rẹ ni ọ̀rọ̀ ìpìlẹ̀ orin mi 55Ní òru èmi rántí orúkọ rẹ, Olúwa, 56nítorí tí mo 57Ìwọ ni ìpín mi, Olúwa: 58Èmi ti wá ojú rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: 59Èmi ti kíyèsi ọ̀nà mi 60Èmi yóò yára, ń kò ni lọ́ra 61Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ẹni búburú dì mí pẹ̀lú okùn, 62Ní àárín ọ̀gànjọ́ òru èmi dìde láti fi ọpẹ́ fún ọ 63Èmi jẹ́ ọ̀rẹ́ sí gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ, 64Ayé kún fún ìfẹ́ rẹ, Olúwa, 65Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ Olúwa. 66Kọ́ mi ní ìmọ̀ àti ìdájọ́ rere, 67Kí a tó pọ́n mi lójú èmi ti ṣìnà, 68Ìwọ dára, ohun tí ìwọ sì ń ṣe rere ni; 69Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn agbéraga ti gbìmọ̀ èké sí mí, 70Ọkàn wọn yigbì kò sì ní àánú, 71Ó dára fún mi kí a pọ́n mi lójú 72Òfin tí ó jáde láti ẹnu rẹ ju iyebíye sí mi lọ 73Ọwọ́ rẹ ni ó dá mi tí ó sì mọ mí; 74Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ máa yọ̀ nígbà tí wọ́n bá rí mi, 75Èmi mọ, Olúwa, nítorí òfin rẹ òdodo ni, 76Kí ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà jẹ́ ìtùnú mi, 77Jẹ́ kí àánú rẹ kí ó tọ̀ mí wá, kí èmi kí ó lè yè, 78Kí ojú kí ó ti àwọn agbéraga 79Kí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ yí padà sí mi, 80Jẹ́ kí ọkàn mi wà láìlẹ́bi sí òfin rẹ, 81Ọkàn mi ń fojú ṣọ́nà nítorí ìgbàlà rẹ, 82Ojú mi kùnà, pẹ̀lú wíwo ìpinnu rẹ; 83Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi dàbí awọ-wáìnì lójú èéfín, 84Báwo ni ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò ṣe dúró pẹ́ tó? 85Àwọn agbéraga wa ihò ìṣubú fún mi, 86Gbogbo àṣẹ rẹ yẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé; 87Wọ́n fẹ́rẹ pa mí rẹ́ kúrò nínú ayé, 88Pa ayé mi mọ́ gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ, 89Ọ̀rọ̀ rẹ, Olúwa, títí láé ni; 90Òtítọ́ rẹ̀ ń lọ dé gbogbo ìran dé ìran; 91Òfin rẹ dúró di òní 92Bí òfin rẹ̀ kò bá jẹ́ dídùn inú mi, 93Èmi kì yóò gbàgbé ẹ̀kọ́ rẹ láé, 94Gbà mí, nítorí èmi jẹ́ tìrẹ 95Àwọn ẹni búburú dúró láti pa mí run, 96Sí ohun pípé gbogbo èmi ti rí òpin; 97Báwo ni èmi ti fẹ́ òfin rẹ tó! 98Àṣẹ rẹ mú mi gbọ́n ju àwọn ọ̀tá mi lọ, 99Èmi ní iyè inú ju gbogbo olùkọ́ mi lọ, 100Èmi ni òye ju àwọn àgbà lọ, 101Èmi ti pa ẹsẹ̀ mi mọ́ nínú gbogbo ọ̀nà ibi 102Èmi kò yà kúrò nínú òfin rẹ, 103Báwo ni ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣe dùn mọ́ mi lẹ́nu tó, 104Èmi rí òye gbà nínú ẹ̀kọ́ rẹ; 105Ọ̀rọ̀ rẹ ni fìtílà sí ẹsẹ̀ mi 106Èmi ti ṣe ìbúra èmi sì ti tẹnumọ́ ọn 107A pọ́n mi lójú gidigidi; Olúwa, sọ mi di ààyè, gẹ́gẹ́ bi ọ̀rọ̀ rẹ 108Olúwa, gba ìyìn àtinúwá ẹnu mi, 109Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ayé mi wà ni ọwọ́ mi nígbà gbogbo, 110Àwọn ẹni búburú ti dẹ okùn sílẹ̀ fún mi, 111Òfin rẹ ni ogún mi láéláé; 112Ọkàn mi ti lé pípa òfin rẹ mọ́ 113Èmi kórìíra àwọn ọlọ́kàn méjì, 114Ìwọ ni ààbò mi àti asà mi; 115Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin olùṣe búburú, 116Gbé mi sókè gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ, 117Gbé mi sókè, èmí yóò sì wa láìléwu; 118Ìwọ kọ gbogbo àwọn tí ó ṣìnà kúrò nínú òfin rẹ, 119Gbogbo àwọn ẹni búburú ní ayé ni ìwọ yọ kúrò bí i ìdàrọ́; 120Ara mi wárìrì ní ìbẹ̀rù nítorí rẹ̀: 121Èmi ti ṣe ohun tí i ṣe òdodo àti ẹ̀tọ́: 122Mú kí àlàáfíà ìránṣẹ́ rẹ dájú: 123Ojú mi kùnà, fún wíwo ìgbàlà rẹ, 124Ṣe pẹ̀lú ìránṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí dídúró ṣinṣin ìfẹ́ rẹ 125Èmi ni ìránṣẹ́ rẹ; ẹ fún mi ní òye 126Ó tó àsìkò fún ọ láti ṣe iṣẹ́, Olúwa; 127Nítorí èmi fẹ́ràn àṣẹ rẹ 128nítorí èmi kíyèsi gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ rẹ̀, 129Òfin rẹ̀ ìyanu ni: 130Ìṣípayá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú ìmọ́lẹ̀ wá; 131Èmi ya ẹnu mi mo sì mí hẹlẹ, 132Yí padà sí mi kí o sì ṣàánú fún mi, 133Fi ìṣísẹ̀ mi múlẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ rẹ, 134Rà mí padà lọ́wọ́ aninilára ènìyàn, 135Jẹ́ kí ojú rẹ kí ó tàn sí ìránṣẹ́ rẹ lára 136Omijé sàn jáde ní ojú mi, 137Olódodo ni ìwọ Olúwa 138Òfin ti ìwọ gbé kalẹ̀ jẹ́ òdodo: 139Ìtara mi ti pa mí run, 140Wọ́n ti dán ìpinnu rẹ wò pátápátá 141Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti ẹni ẹ̀gàn 142Òdodo rẹ wà títí láé 143Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi, 144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; 145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: Olúwa, 146Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí 147Èmi dìde ṣáájú àfẹ̀mọ́júmọ́ èmi ké fún ìrànlọ́wọ́; 148Ojú mi ṣáájú ìṣọ́ òru, 149Gbọ́ ohùn mi ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ìfẹ́ rẹ: Olúwa, gẹ́gẹ́ bí òfin rẹ. 150Àwọn tí ń gbìmọ̀ ìlànà búburú wà ní tòsí, 151Síbẹ̀ ìwọ wà ní tòsí, Olúwa, 152Láti ọjọ́ pípẹ́ wá èmi ti kọ́ nínú òfin rẹ 153Wo ìpọ́njú mi kí o sì gbà mí, 154Gba ẹjọ́ mi rò kí o sì rà mí padà; 155Ìgbàlà jìnnà sí àwọn ẹni búburú 156Ìyọ́nú rẹ̀ tóbi, Olúwa; 157Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn ọ̀tá tí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí mi, 158Èmi wo àwọn ẹlẹ́tàn, inú mi sì bàjẹ́ 159Wo bí èmi ṣe fẹ́ràn ẹ̀kọ́ rẹ; Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ. 160Òtítọ́ ni gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ; 161Àwọn alákòóso ṣe inúnibíni sí mi láìnídìí, 162Èmi yọ̀ nínú ìpinnu rẹ 163Èmi kórìíra mo sì kọ èké ṣíṣe 164Èmi yìn ọ́ ní ìgbà méje lójúmọ́ 165Àlàáfíà púpọ̀ wà fún àwọn tí ó ní ìfẹ́ sí òfin rẹ, 166Èmi yóò dúró de ìgbàlà rẹ, Olúwa, 167Èmi gba òfin rẹ gbọ́, 168Èmi ṣe ìgbọ́ràn sí ẹ̀kọ́ rẹ àti òfin rẹ, 169Jẹ́ kí igbe mi wá sí iwájú rẹ, Olúwa; 170Jẹ́ kí ẹ̀bẹ̀ mi wá sí iwájú rẹ; 171Ètè mi yóò sọ ìyìn jáde, 172Jẹ́ kí ahọ́n mi kọ orin ọ̀rọ̀ rẹ, 173Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ ṣetán láti ràn mí lọ́wọ́, 174Èmi wo ọ̀nà fún ìgbàlà rẹ, Olúwa, 175Jẹ́ kí èmi wà láààyè ki èmi lè yìn ọ́, 176Èmí ti ṣìnà bí àgùntàn tí ó sọnù.

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →