YOR Psalm Kapitel 1

Psalm 1

YOR · Sammenlign · Lyd

1Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà, 2Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú rẹ̀ wà nínú òfin Olúwa 3Ó dàbí igi tí a gbìn sí etí odò tí ń sàn, 4Kò le rí bẹ́ẹ̀ fún àwọn ènìyàn búburú! 5Nítorí náà àwọn ènìyàn búburú kì yóò le è dìde dúró ní ìdájọ́, 6Nítorí Olúwa ń ṣọ́ ọ̀nà àwọn olódodo,

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →