YOR Zechariah Chương 10

Zechariah 10

YOR · So sánh · Âm thanh

1 béèrè òjò nígbà àrọ̀kúrò ni ọwọ́ Olúwa; Olúwa tí o dá mọ̀nàmọ́ná, 2Nítorí àwọn òrìṣà tí sọ̀rọ̀ asán, 3“Ìbínú mi ru sí àwọn darandaran, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti bẹ agbo rẹ̀, 4Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni òkúta igun ilé ti jáde wá, 5Gbogbo wọn yóò sì dàbí ọkùnrin Olúwa wà pẹ̀lú wọn, 6“Èmi o sì mú ilé Juda ní agbára, Olúwa Ọlọ́run wọn, 7Efraimu yóò sì ṣe bí alágbára, Olúwa. 8Èmi ó kọ sí wọn, èmi ó sì ṣà wọ́n jọ; 9Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo tú wọn káàkiri orílẹ̀-èdè: 10Èmi ó sì tún mú wọn padà kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti pẹ̀lú, 11Wọn yóò sì la Òkun wàhálà já, 12Èmi ó sì mú wọn ní agbára nínú Olúwa; Olúwa wí.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →