YOR Nahum Chương 2

Nahum 2

YOR · So sánh · Âm thanh

1Àwọn apanirun ti dìde sí ọ, ìwọ Ninefe. 2Olúwa yóò mú ọláńlá Jakọbu padà sípò 3Asà àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ sì di pupa; 4Àwọn kẹ̀kẹ́ ogun yóò ya bo àwọn pópónà, 5Ninefe yóò ṣe àṣàrò àwọn ọlọ́lá rẹ̀; 6A ó ṣí ìlẹ̀kùn àwọn odò wọ̀n-ọn-nì sílẹ̀, 7A pa á láṣẹ pé ìlú náà, èyí tí a ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ 8Ninefe dàbí adágún omi, 9“Ẹ kó ìkógun fàdákà! 10Òun ti ṣòfò, ó si di asán, ó sì di ahoro: 11Níbo ni ihò àwọn kìnnìún wà 12Kìnnìún tipa ọ̀pọ̀lọpọ̀ fún àwọn ọmọ rẹ̀, 13“Kíyèsi i èmi dojúkọ ọ́,” Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →