YOR Nahum Chương 1

Nahum 1

YOR · So sánh · Âm thanh

1̀rọ̀-ìmọ̀ nípa Ninefe. Ìwé ìran Nahumu ará Elkoṣi. Olúwa sí Ninefe 2Ọlọ́run ń jẹ owú, ó sì ń gbẹ̀san, Olúwa ń gbẹ̀san, ó sì kún fún ìbínú. Olúwa ń gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. 3Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára; Olúwa kì yóò fi àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀ láìjìyà. 4Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ; 5Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀, 6Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀? 7Rere ni Olúwa, 8ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìkún omi ńlá 9Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ̀ lòdì sí Olúwa? 10Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣú 11Láti ọ̀dọ̀ rẹ, ìwọ Ninefe, ni ẹnìkan ti jáde wá Olúwa 12Báyìí ni Olúwa wí: 13Nísinsin yìí ni èmi yóò já àjàgà wọn kúrò ní ọrùn rẹ 14Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe: 15Wò ó, lórí àwọn òkè,

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →