Ordspråksboken 9
1Ọgbọ́n ti kọ́ ilé rẹ̀, 2ó ti fi ilé pọn tí, ó ti fọ̀nà rokà. 3ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè, 4“Jẹ́ kí gbogbo àwọn aláìgbọ́n wọ ibí wá!” 5“Wá, ẹ wá jẹ́ oúnjẹ mi 6Fi ìwà àìmọ̀kan rẹ sílẹ̀ ìwọ yóò sì yè; 7“Ẹnikẹ́ni tí ó bá bá ẹlẹ́gàn wí, kọ lẹ́tà sí àbùkù 8Má ṣe bá ẹlẹ́gàn wí, àìṣe bẹ́ẹ̀ yóò kórìíra rẹ. 9kọ́ ọlọ́gbọ́n ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́, yóò sì gbọ́n sí i 10“Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n, 11Nítorí nípasẹ̀ mi ọjọ́ rẹ yóò gùn 12Bí ìwọ bá gbọ́n, ọgbọ́n rẹ yóò fún ọ ní èrè: 13Òmùgọ̀ obìnrin jẹ́ aláriwo; 14Ó jókòó ní ẹnu-ọ̀nà ilé rẹ̀ 15ó ń pe àwọn tí ó ń kọjá lọ, 16“Jẹ́ kí gbogbo ẹni tí ó jẹ́ aláìlóye súnmọ́ bí!” 17“Omi tí a jí mu dùn 18Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀,