YOR Ordspråksboken Kapitel 5

Ordspråksboken 5

YOR · Jämför · Ljud

1mọ mi, fiyèsí ọgbọ́n mi, 2kí ìwọ sì lè ní ìṣọ́ra 3Nítorí ètè àwọn àjèjì obìnrin a máa sun bi oyin, 4Ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, ó korò ju òróǹró lọ, 5Ẹsẹ̀ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí ọ̀nà ikú 6Kí ìwọ má ba à já ipa ọ̀nà ìyè; 7Nítorí náà, ẹ̀yin ọmọ mi, ẹ dẹtí sí mi, 8Rìn ní ọ̀nà tí ó jìnnà sí ti rẹ̀, 9àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò gbé gbogbo ọlá rẹ lé ẹlòmíràn lọ́wọ́ 10Kí a má ba à fi ọrọ̀ rẹ fún àjèjì ènìyàn, 11Ní ìgbẹ̀yìn ayé rẹ ìwọ yóò kérora, 12Ìwọ yóò wí pé, “Mo ti kórìíra ẹ̀kọ́ tó! 13N kò gbọ́rọ̀ sí àwọn olùkọ́ mi lẹ́nu, 14Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá 15Mu omi láti inú kànga tìrẹ, 16Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà 17Jẹ́ kí wọn jẹ́ tìrẹ nìkan, 18Jẹ́ kí orísun rẹ kí ó ní ìbùkún; 19Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọ, 20Ọmọ mi, èéṣe tí ìwọ ó fi máa yọ̀ nínú ìfẹ́ obìnrin panṣágà, 21Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún Olúwa 22Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn; 23Yóò kú ní àìgba ẹ̀kọ́

Daglig gräns nådd

Uppgradera din plan för att fortsätta använda AI-funktioner med högre dagliga gränser.

Jämför alla planer →