Јеремија 5
1“Lọ sókè àti sódò àwọn òpópó Jerusalẹmu, 2Bí wọ́n tilẹ̀ wí pé, ‘Bí Olúwa ti ń bẹ,’ 3Olúwa, ojú rẹ kò ha wà lára òtítọ́? 4Èmi sì rò pé, “Tálákà ni àwọn yìí; Olúwa, 5Nítorí náà, èmi yóò tọ àwọn adarí lọ, Olúwa 6Nítorí náà, kìnnìún láti inú igbó yóò kọlù wọ́n, 7“Kí ni ṣe tí èmi ó ṣe dáríjì ọ́? 8Wọ́n jẹ́ akọ ẹṣin tí a bọ́ yó, 9Èmi kì yóò ha ṣe ìbẹ̀wò nítorí nǹkan wọ̀nyí?” Olúwa wí. 10“Lọ sí ọgbà àjàrà rẹ̀, kí ẹ sì pa wọ́n run, Olúwa. 11Ilé Israẹli àti ilé Juda Olúwa wí. 12Wọ́n ti pa irọ́ mọ́ Olúwa; 13Àwọn wòlíì wá dàbí afẹ́fẹ́, 14Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Alágbára wí: 15Háà, ẹ̀yin ilé Israẹli,” ni Olúwa wí, 16Apó-ọfà rẹ sì dàbí isà òkú tí a ṣí 17Wọn yóò jẹ ìkórè rẹ àti oúnjẹ rẹ, 18“Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,” ni Olúwa wí, “Èmi kì yóò pa yín run pátápátá. 19Àti pé, nígbà tí àwọn ènìyàn bá sì béèrè wí pé, ‘Kí ni ìdí rẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run wa fi ṣe gbogbo èyí sí wa?’ Ìwọ yóò sì sọ fún wọn wí pé, ‘Ẹ̀yin ti kọ̀ mí sílẹ̀, ẹ sì ń sin ọlọ́run àjèjì ní ilẹ̀ yín. Nísinsin yìí, ẹ̀yin yóò máa sin àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiyín.’ 20“Kéde èyí fún ilé Jakọbu, 21Gbọ́ èyí, ẹ̀yin aṣiwèrè àti aláìlọ́gbọ́n ènìyàn, 22Kò ha yẹ kí ẹ bẹ̀rù mi?” Olúwa wí. 23Ṣùgbọ́n, àwọn ènìyàn wọ̀nyí ní ọkàn líle àti ọkàn ọ̀tẹ̀, 24Wọn kò sọ fún ara wọn pé, Olúwa Ọlọ́run wa, 25Àìṣedéédéé yín mú gbogbo nǹkan wọ̀nyí kúrò, 26“Láàrín ènìyàn mi ni ìkà ènìyàn wà 27Bí àgò tí ó kún fún ẹyẹ, 28wọ́n sanra wọ́n sì ń dán. 29Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n fún èyí bí?” Olúwa wí. 30“Nǹkan ìbànújẹ́ àti ohun ìtara 31Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,