Јеремија 46
1Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Jeremiah wòlíì wá nípa àwọn Orílẹ̀-èdè. 2Nípa Ejibiti. 3“Ẹ múra àpáta, èyí tí ó tóbi, àti èyí tí ó kéré, 4Ẹ di ẹṣin ní gàárì, 5Kí ni nǹkan tí mo tún rí? Olúwa wí. 6“Ẹni tí ó yára kì yóò le sálọ, 7“Ta ni èyí tí ó gòkè wá bí odò Ejibiti, 8Ejibiti dìde bí odò náà, 9Ẹ gòkè wá ẹ̀yin ẹṣin, 10Ṣùgbọ́n ọjọ́ náà jẹ́ ti Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò rú ẹbọ 11“Gòkè lọ sí Gileadi, kí o sì mú ìkunra, 12Àwọn orílẹ̀-èdè yóò gbọ́ nípa ìtìjú rẹ, 13Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó bá Jeremiah wòlíì nì sọ nípa wíwá Nebukadnessari ọba Babeli láti lọ dojú ìjà kọ Ejibiti: 14“Kéde èyí ní Ejibiti, sì sọ ọ́ ní Migdoli, 15Èéṣe tí àwọn akọni rẹ fi ṣubú? Olúwa yóò tì wọ́n ṣubú. 16Wọn yóò máa ṣubú léraléra 17Níbẹ̀ ni wọn ó kígbe pé, 18“Bí èmi ti wà láààyè,” ni ọba, Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé, 19Ìwọ, ọmọbìnrin ti ń gbé Ejibiti 20“Ẹgbọrọ abo màlúù tó lẹ́wà ní Ejibiti 21Àwọn jagunjagun rẹ̀ 22Ejibiti yóò pòṣé bí ejò tí ń sá 23Wọn o gé igbó rẹ̀ lulẹ̀,” ni Olúwa wí, 24A ó dójútì ọmọbìnrin Ejibiti, 25Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí pé: “Èmi yóò rọ̀jò ìyà mi sórí Amoni òrìṣà Tebesi, sórí Farao, sórí Ejibiti àti àwọn òrìṣà rẹ̀ àti sórí àwọn ọba rẹ̀ àti sórí àwọn tó gbẹ́kẹ̀lé Farao. 26Èmi ó sì fi wọ́n lé àwọn tó wá ẹ̀mí wọn lọ́wọ́, lé Nebukadnessari ọba Babeli, ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, Ejibiti yóò sì di gbígbé bí i ti àtijọ́,” ni Olúwa wí. 27“Má bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi, 28Má bẹ̀rù, Jakọbu ìránṣẹ́ mi, Olúwa wí.