YOR Psalm Kapitola 73

Psalm 73

YOR · Porovnať · Audio

1Nítòótọ́ Ọlọ́run dára fún Israẹli, 2Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi, ẹsẹ̀ mi ti yẹ̀ tán; 3Nítorí èmi ń ṣe ìlara àwọn tó ń ṣe féfé 4Wọn kò ṣe wàhálà; 5Wọn kò ní ìpín nínú àjàgà tó ń ṣẹlẹ̀ sí ènìyàn; 6Ìgbéraga ni ọ̀ṣọ́ ọrùn wọn; 7Láti inú ọkàn àrékérekè ni àìṣòdodo ti wá; 8Wọn ń ṣẹ̀sín, wọn sì ń sọ̀rọ̀-òdì ní ti ìnilára, 9Wọ́n ń gbé ẹ̀mí wọn lé ọ̀run 10Nítorí náà àwọn ènìyàn wọn yípadà sí wọn 11Wọ́n wí pé, “Báwo ni Ọlọ́run yóò ṣe mọ̀? 12Bí àwọn ènìyàn búburú ṣe rí nìyí, 13Nítòótọ́ nínú asán ni mo pa ọkàn mi mọ́; 14Ní gbogbo ọjọ́ ni a ń yọ mí lẹ́nu; 15Bí mo bá wí pé, “Èmi ó wí báyìí,” 16Nígbà tí mo gbìyànjú láti mọ èyí, 17títí mo fi wọ ibi mímọ́ Ọlọ́run; 18Lóòtítọ́ ìwọ gbé wọn lórí ilẹ̀ yíyọ́ 19Báwo ní a ti mú wọn lọ sínú ìdahoro yìí 20Bí àlá nígbà tí ènìyàn bá jí, Olúwa, 21Nígbà tí inú mi bàjẹ́ 22mo jẹ́ aṣiwèrè àti aláìlóye; 23Síbẹ̀ mo wà pẹ̀lú rẹ nígbà gbogbo; 24Ìwọ fi ìmọ̀ràn rẹ tọ́ mi 25Ta ni mo ní ní ọ̀run, bí kò ṣe ìwọ? 26Ara mi àti ọkàn mi le è kùnà 27Àwọn tí ó jìnnà sí ọ yóò ṣègbé 28Ṣùgbọ́n ní ti èmi, ó dára láti súnmọ́ Ọlọ́run. Olúwa Olódùmarè ṣe ààbò mi;

Dosiahnutý dennýLimit

Upgradujte svoj balík, aby ste pokračovali v používaní funkcií AI s vyššími dennými limitmi.

Porovnať všetky plány →